Revision control

Copy as Markdown

<?xml version="1.0" encoding="utf-8"?>
<resources xmlns:tools="http://schemas.android.com/tools" xmlns:moz="http://mozac.org/tools">

<string name="mozac_browser_errorpages_page_refresh">Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan sí i</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_generic_title">A kò lè parí ìbéèrè rẹ</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_generic_message"><![CDATA[

Àfikún ìfitónilétí nípa ìsòro tàbí àsìṣe yìí kò sí lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_ssl_title">Ìsomọ́ra Onífọ̀kànbalẹ̀ Kùnà</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_ssl_message"><![CDATA[

ojú-ìwé tí ò ń gbìyànjú àti wò, kò ṣe é fi hàn báyìí nítorí pé ìjẹ́-òtítọ́ data tí a gbà ni a kò lè fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀.

Jọ̀wọ́ kàn sí ẹni tí ó ni ìkànnì náà láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_cert_title">Ìsomọ́ra onífọkànbalẹ̀ kùnà</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_cert_message"><![CDATA[

Ìsòro yìí lè jẹ́ ìfisáfà ṣiṣẹ́ tàbí kí ẹlòmíràn fẹ́ gbáwọ̀ sáfà wọ̀.

Bí o bá ti ṣe àṣeyege àti wọlé sórí sáfà yìí tẹ́lẹ̀ rí, àsìṣe náà lè jẹ́ èyí tí kò ní pẹ́, ó sì le gbìyànjú sí i bó bá yá .

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_cert_advanced">Ìjìnlẹ̀…</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_cert_techInfo"><![CDATA[
Ẹnìkan le máa gbìyànjú àti gbáwọ̀ ìkànnì náà wọ̀, má tẹ̀síwájú.

Ìkànnì ṣe ìfidánilójú ìdánimọ̀ wọn pẹ̀lú ẹ̀rí. %1$s má gbẹ́kẹ̀lé %2$s nítorí pé kìí ṣe ẹni mímọ̀ ni ó fi ìwé-ẹ̀rí rẹ̀ lóde, ìfọ́wọ́sí-ara-ẹni ni ìwé-ẹ̀rí náà jẹ́, tàbí ìkànnì náà kò fi ojúlówó ìwé-ẹ̀rí abàárín ránṣẹ́.
]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_cert_back">Padà Sẹ́yìn (Ìmọ̀ràn tó dára)</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_cert_accept_temporary">Gba Ewu náà kí o sì tẹ̀síwájú</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_hsts_cert_title">Ìkọ̀nì yìí nílò ìsopọ̀ tó pamọ́.</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_hsts_cert_message"><![CDATA[

O kò lè rí abala tí ò ń gbìyànjú láti ṣí yìí nítorí pé ìkànní yìí nílò ààbò.

Ìṣòro yìí lè jẹ́ èyí tó wá láti orí ìkànnì yìí, kò sì sí ohun tí o lè ṣe si láti wá ọ̀nà àbáyọ si.

O sì lè pe àkíyèsí alámòjútó ìkànnì náà sí ìṣòro yíì.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_hsts_cert_advanced">Ní ìlọsíwájú…</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_hsts_cert_techInfo2"><![CDATA[ %1$s gẹ́gẹ́ bíi ètò ààbò tí a pè ní HTTP ààbò ìlọmabọ̀ tó le (HSTS), tó túmọ̀ sí pé %2$s ó lè ní ìbátan pẹ̀lú rẹ̀ nígbà tí ààbò bá wà. O kò lè fi ìyàsọ́tọ̀ kún-un láti ṣàbẹ̀wò sí sáìtì yìí.
]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_security_bad_hsts_cert_back">Padà Sẹ́yìn</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_net_interrupt_title">Akùdé bá ìsomọ́ra náà</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_net_interrupt_message"><![CDATA[

ìtàkùn ìgbáyé so mọ́ra dáadáa, ṣùgbọ́n àkùdé bá ìsomọ́ra náà nígbà tí à ń fi ìfitónilétí ránṣẹ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú sí i.

Ìkànnì náà lè má siṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ tàbí kí ọwọ́ kún un. Gbìyànjú rẹ̀ sí i ní àìpẹ́.

Bí o kò bá lè jẹ́ kí ojú-ìwé rẹ siṣẹ́, yẹ ohun tí data rẹ fi ń siṣẹ́ wò tàbí ìsomọ́ Wi-Fi rẹ.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_net_timeout_title">Àkókò ìsomọ́ ti kọjá</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_net_timeout_message"><![CDATA[

Ìkànnì tí ó bèèrè kò dáhùn sí ìsomọ́ ti o béèrè àti pé ìtàkùn àgbáyé ti dúró iṣẹ́, ó ń dúró fún èsì.

Ǹjẹ́ ó ṣe é ṣe kí sáfà máa dojúkọ ìpè púpọ̀ tàbí kí ó má ṣiṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀? Gbìyànjú bí ó bá yá.

Ǹjẹ́ o ní ìṣòro àti sàwárí àwọn ìkànnì mìíràn? Yẹ ohun tí o fi ṣe àsomọ́ wò.

Ǹjẹ́ ìdáabòbò ohun èlò rẹ tàbí nẹ́tíwòkì jẹ́ láti ọwọ́ ojúlówó tàbí asojú? àsìsẹ ààtò lè nípa lórí wíwá nǹkna lórí ìkànnì.

O sì ní ìsòro síbẹ̀? Kàn sí alákòóso nẹ́tiwọkì rẹ tàbí àpèse íntánẹ́ẹ̀tì rẹ fún ìrànlọ́wọ́.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_connection_failure_title">Kùnà láti somọ́ra</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_connection_failure_message"><![CDATA[

Ìkànnì náà lè má sí ní àrọ́wọ́tó fún ìgbà díẹ̀ tàbí kí ọwọ́ kún un. Gbìyànjú sí i láìpẹ́.

Bí o kò bá lè jẹ́ kí ojú-ìwé siṣẹ́, yẹ ohun èlò data rẹ wò tàbí àsomọ́ Wi-Fi.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_socket_type_title">Èsì tí a kò retí láti ọ̀dọ̀ sáfà</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_socket_type_message"><![CDATA[

Ìkànnì ń fèsì sí nẹ́tíwọ̀kì lọ́nà ti a kò retí àti pé ìtàkùn àgbáyé kò le tẹ̀síwájú.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_redirect_loop_title">Ojú-ìwé náà kò ṣe atọ̀nà dáadáa</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_redirect_loop_message"><![CDATA[

ìtàkùn àgbáyé dáwọ́ àtimú àwọn ohun tí a bèèrè dúró. Ìkànnì náà ń ṣe àtúntọ́sọ́nà lọ́nà tí kò lè parí láéláé.

Ǹjẹ́ o ti ṣo ọ́ di aláìlágbára tàbí dínà àwọn adásiṣẹ́ tí ìkànnì yìí nílò?

Bí gbígba àwọn adásiṣẹ́ ìkànnì yìí kò bá yanjú ìsòro yìí, a jẹ́ pé ó ṣe é ṣe kí ó jẹ́ ìsòro ìfisáfàṣiṣẹ́ ni, kìí sì ṣe ohun èlò rẹ.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_offline_title">Ipò àìsí lórí íntánẹ́ẹ̀tì </string>

<string name="mozac_browser_errorpages_offline_message"><![CDATA[

Ìtàkùn-àgbáyé ń ṣiṣẹ́ lóríipò àìsí lórí íntánẹ́ẹ̀tì, nítorí náà, kò lè so mọ́ ohun tí a bèèrè fún.

Ǹjẹ́ ohun èlò náà wà ní sísomọ́ nẹ́tíwọ̀kì tó ń ṣiṣẹ́?

Tẹ “Gbìyànjú sí i” láti bọ́ sí ipo íntánẹ́ẹ̀tì, kí o si ojú-ìwé náà siṣẹ́ lẹ́ẹ̀kan sí.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_port_blocked_title">Ojú yìí kò ṣiṣẹ́ nítorí ààbò</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_port_blocked_message"><![CDATA[

Àdírẹ́sì tí o bèèrè fún nílò ojú kan pàtó (e.g., mozilla.org:80 fún ojú 80 lórí mozilla.org) ni a máa ń sábà lò fún àwọn ìdí yàtọ̀ sí ìwá nǹkan kíri orí ìkànnì. Ìtàkùn-àgbáyé ti gbégi lé ìbéérè náà fún ààbò rẹ.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_net_reset_title">Ìsomọ́ra di àtúntò </string>

<string name="mozac_browser_errorpages_net_reset_message"><![CDATA[

Akùdé bá òpónà nẹ́tíwọ̀kì nígbà tí ìdúnàándúrà ìsomọ́ra ń lọ lọ́wọ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú sí i.

Ìkànnì náà lè má siṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ tàbí kí ọwọ́ kún un. Gbìyànjú lẹ́yìn ìgbà díẹ̀.

Bí o kò bá lè jẹ́ kí ojú ìwé kankan siṣẹ́, yẹ ohun èlò data rẹ wò tàbí ìsomọ́ Wi-Fi.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unsafe_content_type_title">Ẹ̀yà fáìlì tó léwu</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unsafe_content_type_message"><![CDATA[

Jọ̀wọ́ kàn sí àwọn tí ó ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_corrupted_content_title">Àṣìṣe ìbàjẹ́ àkóónú </string>

<string name="mozac_browser_errorpages_corrupted_content_message"><![CDATA[

Ojú-ìwé tí ò ń gbìyànjú àti wò kò ṣe é fihàn nítorí pé a rí àṣìṣe kan nínú data fífiránṣẹ́.

Jọ̀wọ́ kan sí àwọn tí ó ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_content_crashed_title">Àkóónú ti bàjẹ́</string>
<string name="mozac_browser_errorpages_content_crashed_message"><![CDATA[

Ojú-ìwé tí ò ń gbíyànjú àti wò kò ṣe é fi hàn nítorí pé, a rí àṣìṣe kan nínú ìfidátà ránsẹ́.

Jọ̀wọ́ kàn sí àwọn tó ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_invalid_content_encoding_title">Àṣìṣe ìṣàrokò àkóónú </string>
<string name="mozac_browser_errorpages_invalid_content_encoding_message"><![CDATA[

Ojú-iwé tí ò ń gbìyànjú àti wò kò ṣe é fi hàn nítorí tí ó le ìsọdikékeré alápiṣeégbà tàbí aláìfọwọ́sí.

Jọ̀wọ́ kàn sí àwọn tí wọ́n ni ìkànnì láti fi ìsòro yìí tó wọn létí.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_host_title">A kò rí àdírẹ́sì </string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_host_message"><![CDATA[

Ìtàkùn-àgbáyé kò rí agbàlejò sáfà fún àdírẹ́sì.

yẹ àdírẹ́sì náà wò fún àṣìtẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i
ww.example.com dípò
www.example.com.

Bí o kò bá lè mú kí ojú ìwé kankan ṣiṣẹ́, yẹ ohun èlò data rẹ wò tàbí ìsomọ́ Wi-Fi.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_no_internet_title">Kò sí ìsomọ́ íntánẹ́ẹ̀tì </string>

<string name="mozac_browser_errorpages_no_internet_message">Yẹ àsomọ́ nẹ́tiwọ̀kì rẹ wò tàbí gbìyànjú àti mú ojú-ìwé ṣiṣẹ́ lẹ́yìn ìgbà díẹ̀ </string>

<string name="mozac_browser_errorpages_no_internet_refresh_button">Tún mú un ṣiṣẹ́</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_malformed_uri_title">Àdírẹ́sì aláìṣeégbà </string>
<string name="mozac_browser_errorpages_malformed_uri_message"><![CDATA[

Àdírẹ́sì tí o pèsè kò sí ní ìlànà tí a dámọ̀. Jọ̀wọ́ yẹ àmì ìfi-ọ̀gangan-hàn wò fún àṣìṣe, kì ò sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan sí i.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_malformed_uri_title_alternative">Àdírẹ́sì náà kò ṣe é gbà</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_malformed_uri_message_alternative"><![CDATA[

Àdírẹ́sì ìkànnì ni a sábà máa ń kọ bí i http://www.example.com/

Rí i dájú pé àkámọ́ asùnsọ́wọ́-wájú ni ò ń lò (b.a. /).

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_protocol_title">Ìlànà tí a kò mọ̀ </string>
<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_protocol_message"><![CDATA[

Àdírẹ́sì náà sọ ìlànà kan (e.g., wxyz://) ìtàkùn-àgbáyé kò dá a mọ̀, nítorí náà àtàkùn-àgbáyé kò lè so ó mọ́ ìkànnì.

Ǹjẹ́ ò gbìyànjú àti ní àǹfààní sí ìbánisọ̀rọ̀-alárànbarà tàbí àwọn iṣẹ́ mìíràn tí kìí ṣe alátẹ̀jíṣẹ́? Wo ìkànnì náà fún àwọn ìbéérè tí ó tún kù.

Àwọn ìlànà mìíràn a máa alàgàta amẹ́rọṣiṣẹ́ kí ìtàkùn-àgbáyé tó lè dá wọn mọ̀.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_file_not_found_title">A kò rí fáìlì </string>
<string name="mozac_browser_errorpages_file_not_found_message"><![CDATA[

Ǹjẹ́ a lè ti pa orúkọ nǹkan náà dà, yọ ọ́ kúrò tàbí mú un lọ síbòmíràn?

Ǹjẹ́ àṣìṣe wa lè wà níbi sípẹ́lì, ìlo-lẹ́tà-ńlá, tàbí àṣìtẹ̀ níbi àdírẹ́sì bí?

Ǹjẹ́ o ní ìyọ́nda tótó fún ohun tí ò ń bèèrè?

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_file_access_denied_title">Ìdènà wà sí àṣe sí fáìlì náà </string>
<string name="mozac_browser_errorpages_file_access_denied_message"><![CDATA[

Ó ṣe é ṣe kí wọ́n ti yọ ọ́, gbé e tàbí àṣẹ sí fáìlì lè máa dènà àti wọlé.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_proxy_connection_refused_title">Asojú sáfà kọ asomọ́ra</string>
<string name="mozac_browser_errorpages_proxy_connection_refused_message"><![CDATA[

Ìtàkùn-àgbáyé ni a ṣe lanà tí ó gbọ́dọ̀ lo asojú fáfà, ṣùgbọ́n asojú náà kọ ìsomọ́ra.

Ǹjẹ́ ìfiṣiṣẹ́ asojú ìtàkùn-àgbáyé náà tọ̀nà? Yẹ ààtò wò kí o sì gbìyànjú sí i.

Ǹjẹ́ iṣẹ́ asojú fàyè gba ìsomọ́ra láti ọ̀dọ̀ nẹ́tíwọ̀kì yìí?

O sì ní ìsòro síbẹ̀? Kàn sí alákòóso nẹ́tíwọ̀kì rẹ tàbí olùpèsè íntánẹ́ẹ̀tì rẹ fún ìrànlọ́wọ́.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_proxy_host_title">A kò sí asokú sáfà </string>
<string name="mozac_browser_errorpages_unknown_proxy_host_message"><![CDATA[

A ṣe ìtànkùn-àgbáyé láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú asojú sáfà ṣùgbọ́n a kò rí asojú.

Ǹjẹ́ ìfiṣiṣẹ́ ìtàkùn-àgbáyé tọ̀nà? Yẹ ààtò wò kí o sì gbìyànjú sí i.

Ǹjẹ́ ohun èlò rẹ wà ní ìsomọ́ nẹ́tíwọ̀kì tó ń ṣiṣẹ́?

Ǹjẹ́ o sì ní ìsòro síbẹ̀? Kàn sí asàkòóso nẹ́tíwọ̀kì rẹ tàbí apèsè íntánẹ́ẹ̀tì rẹ fún ìrànlọ́wọ́.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_browsing_malware_uri_title">Ìṣòro ìkànnì mẹ́rọṣisẹ́-onísùtá</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_browsing_malware_uri_message"><![CDATA[

Ìkànnì ní %1$s ni wan ti jábọ̀ pé wọ́n ti kọ lù ú, wọ́n sì ti dènà rẹ̀ nítorí ìdáàbòbò tí o yàn.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_browsing_unwanted_uri_title">Ìṣòro ìkànnì tí a kò fẹ́</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_browsing_unwanted_uri_message"><![CDATA[

Ìkànnì ní %1$s ni wọ́n jábọ̀ pé ó ní amsọṣiṣẹ́ tí a kò fẹ́, wọ́n sì ti dènà rẹ̀ ítorí ìdáàbòbò tí o yàn.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_harmful_uri_title">Ìṣòro ìkànnì tó léwu</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_harmful_uri_message"><![CDATA[

Ìkànnì ní %1$s ni wọ́n fi sùn pé ó jẹ́ ìkànnì tí ó ṣe é ṣe kí ó léwu, wọ́n sì di dènà rẹ̀ nítorí ìdàábòbò tí o yàn.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_phishing_uri_title">Ìṣòro ìkànnì atànnijẹ</string>

<string name="mozac_browser_errorpages_safe_phishing_uri_message"><![CDATA[

Ojú-ìwé ìkànnì yìí %1$s ni wọ́n ti fi sùn gẹ́gẹ́ ìkànnì àtànnijẹ, wọ́n sì ti dènà rẹ̀ nítorí ìdàábòbò tí o yàn.

]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_httpsonly_title">Ìkànnì adánilójú kò sí </string>

<string name="mozac_browser_errorpages_httpsonly_message"><![CDATA[O ti fàyè gba HTTPS-Only Mode láti kún ààbo rẹ nípa, àti ẹ̀dà HTTPS ti %1$s kò sí.]]></string>

<string name="mozac_browser_errorpages_httpsonly_button">Tẹ̀síwájú sí ìkànnì HTTP</string>
</resources>